Ọlọ́run Baba àti Ọlọ́run Ìyá, tí ó jẹ́ Ẹ̀mí àti Ìyàwó, bẹ̀rẹ̀ láti ṣẹ̀dá ohun pọ̀ pọ̀ àti pé yóò tún parí àwọn ẹda pọ̀pọ̀.
Àwọn tí kò lóyé ìlànà ti ìgbàlà sọ pé Maria tàbí àwọn ènìyàn mímọ́ ni Ìyàwó.
Síbẹ̀síbẹ̀, Maria Wundia tàbí àwọn ènìyàn mímọ́ kò lè jẹ́ Ìyàwó ninu Ìfihàn 22 nítorí Ó jẹ́ aya Jesu àti Ẹni tí ó fún wa ní omi ìyè.
Ẹ̀mí àti Ìyàwó tí ó fún wa ní omi ìyè ní àyé ti Ẹ̀mí Mímọ́ ni Ọlọ́run Baba àti Ọlọ́run Ìyá.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy