Bí ó ti wù kí ó rí, Bíbélì tún sọ pé bí wọ́n bá rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ gbà, ọkàn wọn yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ara wọn yóò ṣègbé.
A nílò láti ṣe ìbaptisí ní orukọ Olùgbàlà tó ní aṣẹ láti dáríji àwọn ẹ̀ṣẹ̀ àti fúnni ní ìyè àìnípẹ̀kun.
Ìjọ kan ṣoṣo tó ń fúnni ní ìbaptisí ní orukọ Ọlọrun Baba, Jehofa, Ọlọrun Ọmọ, Jesu, àti Ọlọrun Ẹ̀mí Mímọ́, Kristi Ahnsahnghong, ni Ìjọ Ọlọrun.
Ẹni tí ó ba ṣẹ́gun, òun ni èmi ó fi ṣe ọ̀wọ́n nínú tẹmpili Ọlọ́run mi, òun kì yóò sì jáde kúrò níbẹ̀ mọ́: èmi ó sì kọ orúkọ Ọlọ́run mi sí i lára, àti orúkọ ìlú Ọlọ́run mi, tí i ṣe Jerusalẹmu tuntun, tí ó ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run mi wá: àti orúkọ tuntun ti èmi tìkára mi. Ìfihàn 3:12
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy