Ọlọ́run wá sí ayé yìí nínú ẹran ara nígbà kejì ní ọjọ́ òtútù ní ọdún 1918, gẹ́gẹ́ bí àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì. Ó ṣe iṣẹ́ ìkọ́lé, ó sì ń waásù òtítọ́ májẹ̀mú tuntun nígbà tí ó ń gbé ìgbésí ayé takuntakun, síbẹ̀ àwọn ènìyàn kẹ́gàn Rẹ̀, wọ́n sọ pé kì í ṣe Ọlọ́run.
Síbẹ̀sibẹ̀, ọ̀nà láti ṣe ìdánimọ̀ Ẹni tí o jẹ́ ìmọ̀ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, kìí ṣe nípa ọgbọ́n ènìyàn ṣùgbọ́n nípa Bíbélì. Kristi Ahnsahnghong fún wa ní ìyè àìnípẹ̀kun nípasẹ̀ ọtí-waini ti májẹ̀mú titun Ìrékọjá; Òun ni Ọlọ́run wa àti Kristi tí o tún wá fún ìgbàlà wa.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy